YBH 595

OLUWA ni Oba

1. OLUWA ni Oba;
E bo Oluwa nyin;
Eni kiku, s’ ope,
Y’ ayo’ segun titi;
Gb’ okan at’ ohun nyin s’ oke.
“E yo,” mo sit un wi “E yo.”

2. Olugbala joba,
Olorun otito;
‘Gbat’ o we ‘se wa nu,
O goke lo joko;

3. O mbe lodo Baba,
Titi gbogbo ota,
Yio teri won ba,
Nipa ase Tire.

4. Yo n’ ireti ogo,
Onidajo mbo wa;
Lati mu ‘ranse Re
Lo ‘le aiyeraiye.
A fe gb’ ohun Angel’ nla na,
Ipe y’o dun wipe, “E yo.”

(Visited 414 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you