1. MO feran iwe oro Re;
O f’ imole at’ ayo fun
Okan okun on ‘banuje!
Oro Re t’ oan mi wiwo;
Eru Re ko jeki nsirin,
‘Leri Re m’ okan mi simi.
2. Eru Re ji mi n’n’ ogbe mi,
O so ‘bit’ ewu mi gbe wa;
Sugbon Oluwa, oro Re
L’ o so okan mi di mimo,
L’ o te ori ese mi ba,
L’ o si m’ ere nla wa l’ ofe.
3. Tani mo ebi okan re?
Dari ‘sise koko ji mi,
Gba mi low ese agidi,
K’ O si gba iyin ‘rele mi,
Fun aika ‘we ore-ofe
At’ eri ise Re lasan.
(Visited 227 times, 1 visits today)