YBH 603

JESU b’ oluso, ma sin wa

1. JESU b’ oluso, ma sin wa,
A nfe, ki Re pupo;
F’ onje didara Re bow a,
Tun agbo Re se fun wa;
Olugbala
O ra wa, Tire l’ a se.

2. O se ‘leri lati gba wa,
Pel’ ese at’ aini wa;
O l’ anu lati fi wow a,
Ipa lati da wa n’de;
Olugbala
O ra wa, Tire l’ a se.

3. Je k’ a tete w’ ojure Re,
K’ a se ‘fe Re ni kutu;
Oluwa at’ Olugbala,
F’ ife Re kun aiya wa;
Olugbala
O ra wa, Tire l’ a se.

(Visited 2,911 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you