YBH 626

JE ran orun kekere nibiti o nlo

1. JE ran orun kekere nibiti o nlo,
Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye,
‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro,
B’ iwo ba je ‘mole njojumo.

Refrain
Je mole kekere b’ o ti wu k’ o mo,
Je mole t’ o dara wo ‘nu okunkun,
E o ri b’ okukun yio ti yara lo,
B’ iwo ba je mole njojumo.

2. Je ran kekere nibiti o nlo,
Ran, a ran fun Jesu Imole didan,
Omo kekere le m’ aiye ese mole,
Ran mole wura sinu aiye.

Refrain
Je mole kekere b’ o ti wu k’ o mo,
Je mole t’ o dara wo ‘nu okunkun,
E o ri b’ okukun yio ti yara lo,
B’ iwo ba je mole njojumo.

3. Je ran orun kekere, mole kedere,
Enia n’ tosi re le nu s’ okun aiye,
O le se ranwo lati l’ okunkun lo,
Mu won to Jesu ti se Mole.

Refrain
Je mole kekere b’ o ti wu k’ o mo,
Je mole t’ o dara wo ‘nu okunkun,
E o ri b’ okukun yio ti yara lo,
B’ iwo ba je mole njojumo.

(Visited 116 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you