YBH 635

NWON duro fun ete kan

1. NWON duro fun ete kan
Nwon gbo t’Olorun;
Bola fun Olotito
K’a nyin egbe Daniel –

Refrain
Ki a se bi Daniel,
K’a fi igboya
Pa ete otito kan
T’o ma han nigbangba.

2. Fun awon ti o nsubu
Ti ko n’igboya
Aye isegun ti wa
Ninu egbe Daniel.

Refrain
Ki a se bi Daniel,
K’a fi igboya
Pa ete otito kan
T’o ma han nigbangba.

3. Awon ota enia
T’o nrin kakiri
Y’o subu l’ogedengbe
Niwaju egbe yi.

Refrain
Ki a se bi Daniel,
K’a fi igboya
Pa ete otito kan
T’o ma han nigbangba.

4. Gbe asia Krist soke
E k’a lo segun,
Egbe esu ni a ngan
K’a ki egbe Daniel.

Refrain
Ki a se bi Daniel,
K’a fi igboya
Pa ete otito kan
T’o ma han nigbangba.

(Visited 181 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you