YBH 638

GBATI ipe Oluwa ba dun

1. GBATI ipe Oluwa ba dun
T’ akoko ba si pin,
T’ imole owuro mimo ntan lailai;
Gbat’ awon t’ a ti gbala,
Y’o pejo s’ oke odo na.

Refrain
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wan be,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wa nbe.

2. L’ oro daradarat’ awon
Oku mimo y’o dide,
T’ ogo ajinde Jesu o je ti won;
Gbat’ awon ayanfe Re y’o
Pejo nile lok’ orun,
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wan be.

Refrain
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wan be,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wa nbe.

3. Jek’ a sise f’ Oluwa lat’
Owuro titi d’ ale,
Ka soro ‘fe ‘yanu at’ itoju Re;
Gbati aiye ba d’ opin t’ ise
Wa si pari nihin,
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wa nibe.

Refrain
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wan be,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun,
Gbat’ a npe oruko lohun ngo wa nbe.

(Visited 5,610 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you