YBH 639

IJA ti de, ipe sin dun kikankikan

1. IJA ti de, ipe sin dun kikankikan,
“Wo ‘hamora!” nigbe jake-jado;
Oluwa omo-ogun nlo si isegun,
Ko pe ti segun Krist’ y’o farahan.

Refrain
Ija ti de, Krsitian ologun,
L’ ojukoju n’opo ija
B’ opagun ti nfe;
Ti hamora ndan, Are, ebi koju loni!
Ija ti de, ma sise sare;
Se akoni n’agbara Re
F’ Olorun l’a ja, ab’ opagun Re,
Ao korin ‘segun nikehin!

2. Ija ti se, om’ ogun oto e dide!
Jehofa nsaju, isegun daju;
E d’ ihamora t’ Olorun ti fi fun nyin,
N’ agbara Re fi ori ti d’opin.

Refrain
Ija ti de, Krsitian ologun,
L’ ojukoju n’opo ija
B’ opagun ti nfe;
Ti hamora ndan, Are, ebi koju loni!
Ija ti de, ma sise sare;
Se akoni n’agbara Re
F’ Olorun l’a ja, ab’ opagun Re,
Ao korin ‘segun nikehin!

3. Oluwa nto nyin lo si segun t’o daju;
Ileri Re ti han n’ ila-orun;
Ile gbogbo y’o f’ iyin f’ ogo ‘ruko Re,
Owuro y’o mu alafia de.

Refrain
Ija ti de, Krsitian ologun,
L’ ojukoju n’opo ija
B’ opagun ti nfe;
Ti hamora ndan, Are, ebi koju loni!
Ija ti de, ma sise sare;
Se akoni n’agbara Re
F’ Olorun l’a ja, ab’ opagun Re,
Ao korin ‘segun nikehin!

(Visited 185 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you