1. IWO ha nberu p’ ota yio segun?
Okun su lode o sis u ju ninu?
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
Refrain
Jeki ‘ran orun wole.
Jeki ‘ran orun wole.
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
2. Igbagbo re nkere ‘nu ‘ja t’ iwo fe?
Olorun ko ha gbo adura re bi?
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
Refrain
Jeki ‘ran orun wole.
Jeki ‘ran orun wole.
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
3. Iwo fe fi ayo lo s’ oke orun?
Ko si orun mo bikose imole?
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
Refrain
Jeki ‘ran orun wole.
Jeki ‘ran orun wole.
Si ferese ati ilekun sile,
Jeki ‘ran orun wole.
(Visited 202 times, 1 visits today)