YBH 642

JESU fe k’ emi je ‘mole

1. JESU fe k’ emi je ‘mole,
Ki ntan lojojumo;
Nibi gbogbo kin le wu On,
N’ ile, ni skul, l’ode.
Imole, imole,
Jesu fe’ k’ emi je ‘mole;
Imole, imole,
L’emi o je fun Jesu.

2. Jesu fe ki emi feran,
Gbogb’ ohun ti mo ri,
Ki nfi itara at’ ayo,
T’ omode Re le je,

3. Mo le se ‘mole fun Jesu,
Bi mo ba gbiyanju;
Ki nsi sin On nigbagbogbo,
Ki mba On gbe l’ orun,

(Visited 689 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you