GBOGBO aiye ti nu s’ okunkun ese
Imole aiye ni Jesu!
B’ iran orun l’ osan gangan l’ ogo Re,
Imole aiye ni Jesu,
Refrain
Wa ‘nu ‘mole,
Ti o tan fun o,
Didun-didun l’ o tan s’ ori mi;
O ti m’emi afoju riran;
Imole aiye ni Jesu!
2. Ko ‘s okunkun fun wa t’ o wa t’ o wa ‘nu Jesu,
Imole aiye ni Jesu!
A nrin n’ imole b’ a ntel’ amona wa,
Imole aiye ni Jesu.
Refrain
Wa ‘nu ‘mole,
Ti o tan fun o,
Didun-didun l’ o tan s’ ori mi;
O ti m’emi afoju riran;
Imole aiye ni Jesu!
3. Eni okunkun t’ ese ti fo l’ oju,
Imole aiye ni Jesu!
Lo we nip’ ase Re imole y’o de,
Imole aiye ni Jesu!
Refrain
Wa ‘nu ‘mole,
Ti o tan fun o,
Didun-didun l’ o tan s’ ori mi;
O ti m’emi afoju riran;
Imole aiye ni Jesu!
4. A ko fe ‘mole orun l’ orun l’ a gbo,
Imole aiye ni Jesu!
Odagutan n’ orun ilu Olorun,
Imole aiye ni Jesu!
Refrain
Wa ‘nu ‘mole,
Ti o tan fun o,
Didun-didun l’ o tan s’ ori mi;
O ti m’emi afoju riran;
Imole aiye ni Jesu!