1. MASE f’oiya ohun t’ o le de,
Olorun y’o so o;
Duro labe iye Re,
Olorun y’o so o.
Refrain
Olorun y’o so o,
Lojo gbogbo l’ ona gbogbo;
On y’o ma toju re,
Olorun y’o so o.
2. Lojo ise t’ are m’ okan re,
Olorun y’o so o;
Gbat’ ewu wa l’ oju ona re,
Olorun y’o so o.
Refrain
Olorun y’o so o,
Lojo gbogbo l’ ona gbogbo;
On y’o ma toju re,
Olorun y’o so o.
3. Eyikeyi t’ idanwo le je,
Olorun y’o so o;
Simi alare lor’ aiya Re,
Olorun y’o so o.
Refrain
Olorun y’o so o,
Lojo gbogbo l’ ona gbogbo;
On y’o ma toju re,
Olorun y’o so o.
(Visited 1,497 times, 3 visits today)