YBH 655

O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo

1. O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo?
A we o nin’ ej Odagutan?
Iwo ha ngbekele ore-ofe Re?
A we o nin’ ej Odagutan?

Refrain
A we o?
Nin eje
Nin’ ej’ Odagutan fun okan
Aso re ha funfun
O si mo laulau?
A we o nin’ ej’ Odagutan?

2. O mba Olugbala rin lojojumo?
A we o nin’ ej’ Odagutan?
O simi le Eniti a kan mo ‘gi?
A we o nin’ ej’ Odagutan?

Refrain
A we o?
Nin eje
Nin’ ej’ Odagutan fun okan
Aso re ha funfun
O si mo laulau?
A we o nin’ ej’ Odagutan?

3. Aso re funfun lati pad’ Oluwa?
O mo lau nin’ ej’ Odagutan?
Okan re mura fun ‘le didan loke?
K’ a we o nin ej’ Odagutan?

Refrain
A we o?
Nin eje
Nin’ ej’ Odagutan fun okan
Aso re ha funfun
O si mo laulau?
A we o nin’ ej’ Odagutan?

(Visited 8,420 times, 4 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you