1. WO kakiri f’ enit’ o s’ alaini,
R’ enia lowo loni!
Bi ‘ranlowo na si tile kere,
R’ enia lowo loni!
Refrain
R’ enia lowo loni,
Enia lona aiye yi;
Mu ‘banuje d’ opin,
S’ ore alailore,
A! r’ enia lowo loni!
2. Opo l’o nso oro imu ‘nu dun,
R’ enia lowo loni!
Je k’ aiye gbo ise ti ‘won ni je,
R’ enia lowo loni!
Refrain
R’ enia lowo loni,
Enia lona aiye yi;
Mu ‘banuje d’ opin,
S’ ore alailore,
A! r’ enia lowo loni!
3. Opo l’ o nku lo fun eru wuwo,
R’ enia lowo loni!
‘Banuje nt’ awon kan nibikibi,
R’ enia lowo loni!
Refrain
R’ enia lowo loni,
Enia lona aiye yi;
Mu ‘banuje d’ opin,
S’ ore alailore,
A! r’ enia lowo loni!
4. Okan wa ti pami nin’ are,
R’ enia lowo loni!
Enikan wa lati to lo s’ orun,
R’ enia lowo loni!
Refrain
R’ enia lowo loni,
Enia lona aiye yi;
Mu ‘banuje d’ opin,
S’ ore alailore,
A! r’ enia lowo loni!