1. NKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le,
Ko tun si ona miran;
Nko le ri ilekun imole na
Bi nko si l’ ona agbelebu.
Refrain
S’ ile l’ on’ agbelebu,
S’ ile l’ on’ agbelebu,
O dun lati mo bi mo tin lo pe,
S’ ile l’ on’ agbelebu.
2. Nko le sai gb’ ona ti eje ti tasi,
Ona t’ Olugbala to;
Bi mo fe d’ oke mimo giga na
N’ ile okan lod’ Olorun.
Refrain
S’ ile l’ on’ agbelebu,
S’ ile l’ on’ agbelebu,
O dun lati mo bi mo tin lo pe,
S’ ile l’ on’ agbelebu.
3. Nje mo ki ona ara, ” Odigbose”
La I maser in n’be mo;
Oluwa mi npe, mo si nwa ile
Nib’ On duro t’ ilekun si.
Refrain
S’ ile l’ on’ agbelebu,
S’ ile l’ on’ agbelebu,
O dun lati mo bi mo tin lo pe,
S’ ile l’ on’ agbelebu.
(Visited 132 times, 1 visits today)