YBH 69

IFE Re da wa si loni

1. IFE Re da wa si loni,
L’ are a si dubule;
Ma so wa n’ idake orun,
K’ ota ma yow a l’enu:
Jesu, se Olutoju wa,
Iwo l’ o dun gbekele.

2. Ero at’ alejo l’ aiye,
A ngb’ arin awon ota!
Yo wa, at’ ile wa l’ ewu,
L’ apa Re ni k’a sun si:
N’ ijo iyonu aiye pin,
K’ a le simi lodo Re.

(Visited 2,088 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you