1. OKAN mi, tun rohin
Enit anu Re, po,
T’ ibinu Re ki ru Kankan,
T’ o yara mu suru.
2. Ipa Re t’ ese wa;
Anu ifiji Re,
B’ ila orun si iwo re
Si m’ ese wa kuro.
3. Bi orun ti ga ju
Ile ti a nte lo,
Beni oro ore Re po
Ju ero giga wa.
(Visited 175 times, 1 visits today)