1. YIN ‘Luwa, okan mi;
Ki gbogbo inu mi,
Ba mi yin oruko Eni
T’ ife Re po julo.
2. Yin ‘Luwa, okan mi;
Ma je k’ anu Re sun
Ninu igbagbe, k’ o si ku
Nipa aim’ ore re.
3. On l’ O fe’ ese re ji,
L’ O mu ‘rora re san;
On l’ O wo gbogbo arun re
L’ O tun fun o l’ okun.
4. O f’ ife j’ aiye re
Gbat a ra o n’boji;
Ent’t’ ogb’ okan mi ninu ‘parun
N’ ipa lati gbala.
(Visited 323 times, 1 visits today)