1. OLORUN l’ abo eni Re,
Nigba iji iponju de:
K’ awa to se aroye wa,
A! saw o t’ On t’ iranwo Re.
2. B’ agbami riru mbu soke,
Okan wa mbe l’ Alafia;
Nigb’ orile at’ etido,
Ba njaya riru omi na.
3. Iwe owo ni, oro Re,
Kawo ibinu fufu wa;
Oro Re m’ Alafia wa,
O f’ ilera f’ okan are.
(Visited 339 times, 1 visits today)