1. T’ OLORUN n’ ijoba gbogbo
Oril-ede, e korin ‘yin:
E so t’ ipa Re to tobi;
Ola Re y’o m’ orin yin dun.
2. O nsan ara lat’ orun wa;
Oruko Re nro li orun:
Omo ore-ofe, e yin;
Enyin mimo, yo l’ oju Re.
3. Olorun ni isimi wa:
On l’ Oba, kede ola Re;
‘Gbat’ eru nde, t’ ilu nsare,
On l’ agbara awa Tire.
(Visited 356 times, 1 visits today)