YBH 87

AYO b’ aiye: Oluwa de

1. AYO b’ aiye: Oluwa de!
K’ aiye gba Oba re;
K’ okan gbogbo pes’ aye fun,
Ki gbogb’ eda korin.

2. Ayo b’ aiye: Jesu joba;
Ki enia korin;
Gbati ohun gbogbo l’aiye
Tun nro iro ayo

3. K’ ese at’ ikanu ye wa,
K’ ile ye hue gun;
O wa lati da ibukun
Sori egun gbogbo.

4. O nf’ otito joba l’ aiye
O si m’ oril’ ede
Jeri ogo at’ oto Re,
At’ iyanu ‘fe Re.

(Visited 1,505 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you