YBH 89

WO oju sanma ohun ni

1. WO oju sanma ohun ni.
Wo lila orun oro.
Ji l’ oju orun, okan mi,
Dide k’ o si ma sora;
Olugbala
Tun npada bow a s’ aiye.

2. O pe ti mo ti nreti Re,
L’ are l’ okan mi nduro,
Aiye ko ni ayo fun mi,
Nibiti ko tan ‘mole.
Olugbala
‘Gbawo n’ Iwo o pada?

3. Igbala mi sunm’ etile,
Oru fere koja na,
Je ki nwa n’ipo irele,
Je ki ns’ afojusona Re,
Olugbala
Titi ngo fi r’ oju Re.

4. Je ki fitila mi ma jo,
Ki nma sako kiri mo,
Ki nsa ma reti abo Re,
Lati mu mi lo s’ ile;
Olugbala
Yara k’ O ma bo Kankan.

(Visited 282 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you