1. ODE, Kristi Oluwa,
Lat’ ibugbe Re l’ orun,
Lat’ ite alafia.
O wa si aginju wa.
2. Alade Alana
De, lati ru ‘ponju wa;
O de, lati f’ imole,
Le okun oru wa lo.
(Visited 421 times, 1 visits today)
1. ODE, Kristi Oluwa,
Lat’ ibugbe Re l’ orun,
Lat’ ite alafia.
O wa si aginju wa.
2. Alade Alana
De, lati ru ‘ponju wa;
O de, lati f’ imole,
Le okun oru wa lo.
We promise not to spam you