YBH 98

WA enyin oloto

1. WA enyin oloto
L’ ayo at’ isegun
Wa kalo, wa kalo si Betlehem;
Wa kalo wo o!
Oba awon Angeli!
E wa kalo juba Re,
E wa k’ a lo juba Kristi Oluwa.

2. Olodumare ni,
Imole Ododo,
Ko si korira inu Wundia;
Olorun papani
Ti a bi, ti a ko da;

3. Angeli, e korin,
Ko rin itoye Re;
Ki gbogbo eda orun si gberin:
Ogo f’ Olorun
Li oke orun,

4. Nitoto, a wole
F’ Oba t’ a bi loni;
Jesu, Iwo l’ awa nfi ogo fun:
‘Wo Omo Baba,
T’ o m’ ara wa wo!

(Visited 3,386 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you