JEKI m’ n’ ipo mi lodo Re
JEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba.
Read hymn : JEKI m’ n’ ipo mi lodo ReJEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba.
Read hymn : JEKI m’ n’ ipo mi lodo ReA! NWON ti gun s’ ebute, L’ oke orun; L’ oke orun; Ebi ko ni pa won mo, Nwon bo lowo irora,
Read hymn : A! NWON ti gun s’ ebuteA! RO ti ibugbe orun, Li eba odo imole, Nibit’ awon mimo wa l’ aiku, T’ a wo won li aso funfun.
Read hymn : A! RO ti ibugbe orunGBAT’ aiye yi ba koja, Ti orun re ba si wo, Ti a ba wo ‘nu ogo, T’ a bojuwo ehin wa;
Read hymn : GBAT’ aiye yi ba kojaOJU ko ti ri, eti ko ti gbo Ese t’ Olugbala pa f’ enia Re, Awon ti O feran, tin won feran Re, Ti nwon nfi ayo sin ninu ile Re.
Read hymn : OJU ko ti ri, eti ko ti gboPARADISE! Paradise! Tani ko fe simi? Tani ko fe ‘le ayo na, Ile alabukun;
Read hymn : PARADISE! Paradise!ASORO ile ‘bukun ni Ile didan, at’ ile ewa ‘Gbagbogbon l’ a nso t’ogo re; Y’o ti dun to lati de ‘be!
Read hymn : ASORO ile ‘bukun niF’ AWON enia Re t’ o lo ‘simi Awon ti o f’ igbagbo jewo Re, Ki yin oruko Re, Olugbala, Alleluya!
Read hymn : F’ AWON enia Re t’ o lo ‘simiOKE kan mbe jina rere, Lehin odi ilu, Nibit’ a kan Oluwa mo, Enit’ O ku fun wa.
Read hymn : OKE kan mbe jina rere“LAI lodo Oluwa!” Amin, beni k’o ri, Iye wa ninu oro na, Aiku ni titi lai,
Read hymn : LAI lodo OluwaLEHIN aiye buburu yi, Aiye ekun on osi yi, Ibi rere kan wa, Ayipada ko si nibe?
Read hymn : LEHIN aiye buburu yiALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye;
Read hymn : ALABUKUN n’nu JesuAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu;
Read hymn : AWON mimo! Ija nwon pinTAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi?
Read hymn : TAL’ awon wonyi b’ iranwo,EGBEGBERUN aimoye Nwon wo aso ala, Ogun awon t’a rapada Nwon kun ‘bi ‘mole naa;
Read hymn : EGBEGBERUN aimoyeOPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye.
Read hymn : OPO ikan omiMASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa.
Read hymn : MASE huwa eseGBATI Samueli ji To ‘igb’ ohun Eleda Ni gbolohun kokan, Ayo re ti po to
Read hymn : GBATI Samueli jiOJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re.
Read hymn : OJ’ oni loJESU Onirele, Omo Olorun: Alanu, Olufe, Gbo ‘gbe omode.
Read hymn : JESU OnireleGB’ adura wa Oluwa, F’ awon omo t’ O fun wa, Pin wa ninu ‘bukun Re, Si fun won l’ ayo l’ orun.
Read hymn : GB’ adura wa OluwaOLORUN Bethel, Eniti O mbo awon Tire; Enit’ o mu baba wa la Ojo aiye won ja.
Read hymn : OLORUN Bethel, EnitiJESU pe omode, O gbe won s’ aiya Re; O f’ owo Re gba won mora, O si sure fun won.
Read hymn : JESU pe omode