OLUWA ni Oba
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni Oba643 hymns
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni ObaOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa.
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re.
Read hymn : OLUWA sokaleOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere.
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu,
Read hymn : OLUWA wa mimoOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiOLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re.
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReOLUWA, a wa ‘do, Re, L’ese Re l’ a kunle si; A! ma kegan ebe wa, A o wa O lasan bi?
Read hymn : OLUWA, a wa ‘do, Re,OLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je.
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiOLUWA, Baba orun, B’ oju woo mo-‘do Re Ti nro t’ igbe aiye re, Ati ipo re si O.
Read hymn : OLUWA, Baba orunOLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku.
Read hymn : OLUWA, bawo l’ okan miOLUWA, b’ agbowode ni, Mo gb’ okan mi le O; Oluwa, f’ ore-ofe wi, K’ O se anu fun mi.
Read hymn : OLUWA, b’ agbowode niOLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi;
Read hymn : OLUWA, iji nfe s’ okeOLUWA, isimi Re dun; Sugbon t’ oke ju ti aiye lo; Sibe pelu ‘reti ayo Li okan ongbe wa nsare.
Read hymn : OLUWA, isimi Re dunOLUWA, Iwo l’ awa npe, A kunle siwaju ‘te Re, Nibo l’ alailera ‘ba lo, ‘Wo nikan ni nwon le kepe.
Read hymn : OLUWA, Iwo l’ awa npeOLUWA, jeki ore Re, To ‘lu wa pel’ agbara Re; K’ o le m’ eje ife re wa, Fun Iwo Olugbala wa.
Read hymn : OLUWA, jeki ore ReOLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni.
Read hymn : OLUWA, ki s’agbara miOLUWA, ma m’ oju kuro Lodo emi t’ o ny’ ile, Ti nsokun ese aiye mi, N’ ite anu ife Re.
Read hymn : OLUWA, ma m’ oju kuroOLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi.
Read hymn : OLUWA, mo gbo pe IwoOLUWA, nje ‘dariji Re Yio gb’ eni bi emi? Nje, O gbe ese mi kuro O f’ erin bukun mi?
Read hymn : OLUWA, nje ‘dariji ReOLUWA, Ob’ Alase, A wole ni ese Re; Gbo igbe itara wa, Bi O ba r’ oju, ao ku.
Read hymn : OLUWA, Ob’ AlaseOLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale wa dun.
Read hymn : OLUWA, ojo t’ O fun wa pinOLUWA, sanu, dariji; Da okan t’o yipada si; Ki sip e anu Re tobi Elese ko le ro mo O?
Read hymn : OLUWA, sanu, dariji