GBAT’ oju mi ba se peki
GBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi,
Read hymn : GBAT’ oju mi ba se pekiGBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi,
Read hymn : GBAT’ oju mi ba se pekiOKAN mi, oju re tun ri Afemo ju ojo; Lekan si, korin, ohun mi S’ Oba t’ O je loke.
Read hymn : OKAN mi, oju re tun riNIGBAT’ imole owuro Ba nti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi!
Read hymn : NIGBAT’ imole owuroKRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun;
Read hymn : KRIST, ologo, ololaOTUN ife l’ o nfarahan, Bi a ti nji l’ ojojumo, Lat’ inu orun at’ okun, A ji s’ agbara at’ ero.
Read hymn : OTUN ife l’ o nfarahanJESU, Oluwa or’-ofe, ‘Wo imole oju Baba, Kanga ‘mole aiyeraiye, T’ ase Re l’ okun ale lo.
Read hymn : JESU, Oluwa or’-ofeNINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba.
Read hymn : NINU gbogbo ewu oruOLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise.
Read hymn : OLUWA mi, mo njade loMIMO, mimo, mimo! Olodumare! Ni kutukutu n’Iwo o gbo orin wa; Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo! Ologo meta lai, Olubukun!
Read hymn : MIMO, mimo, mimo! Olodumare!MO fe iyera s’ apakan Kuro l’ ero t’ aiye, Ki nf’ akoko iwo orun Kunle gba adura.
Read hymn : MO fe iyera s’ apakanJE ni imole ojo Para kuro loju mi, Lala mi rekoja lo, Ngo ba Oluwa soro.
Read hymn : JE ni imole ojoLAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa.
Read hymn : LAT’ ori pepe okan waK’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waOJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su.
Read hymn : OJO oni lo tanWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo.
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoBABA, a tun pade l’ oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re; Si O l’ a tun fe gb’ ohun wa s’ oke Lati wa anu, lati ko ‘rin ‘yin.
Read hymn : BABA, a tun pade l’ oko JesuIWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re.
Read hymn : IWO imole okan miOLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale wa dun.
Read hymn : OLUWA, ojo t’ O fun wa pinL’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo, Nwon gbe abirun wodo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ayo lo le won
Read hymn : L’ OJU ale, ‘gbat’ orun woIFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu:
Read hymn : IFE Re da wa si loniORUN si nyara wo, Ojo nku lo; K’ ife ko ji dide, K’ o rubo asale.
Read hymn : ORUN si nyara woOGO f’ Olorun l’ ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re.
Read hymn : OGO f’ Olorun l’ ale yiJESU, bukun wa k’ a to lo: Gbin oro Re si aiya wa: K’ o si mu k’ ife gbigbona Kun okan ilowo wa:
Read hymn : JESU, bukun wa k’ a to lo