ARA n’nu Krist’, nitori Re
ARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori Re643 hymns
ARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori ReARA, b’ a ko tile gbo Ohun kan lat’ oke wa; Sibe a mo pe loni, Gbogbo ‘rora tan fun o.
Read hymn : ARA, b’ a ko tile gboARE mu o, aiye su o, Lala po fun o? Jesu ni, “Wa si odo, Mi, K’ o simi.”
Read hymn : ARE mu o, aiye su oASAN n’ ireti t’ enia ko Le ori ise won: A bi won pel’ okan eri, Ebi si n’ iwa won.
Read hymn : ASAN n’ ireti t’ enia koASORO ile ‘bukun ni Ile didan, at’ ile ewa ‘Gbagbogbon l’ a nso t’ogo re; Y’o ti dun to lati de ‘be!
Read hymn : ASORO ile ‘bukun niATI gbo iro didun, Jesu le gba ni la, Ji ‘se na yi aiye ka, Jesu le gba ni la,
Read hymn : ATI gbo iro didunAWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u.
Read hymn : AWA nbebe fun ‘le waAWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu;
Read hymn : AWON mimo! Ija nwon pinAYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa.
Read hymn : AYIN O, Oluranwo waAYO awon ti to, T’ o gb’ Olugbala gbo, T’o to isura nwon si oke Ahon ko le s’ adun
Read hymn : AYO awon ti toAYO b’ aiye: Oluwa de! K’ aiye gba Oba re; K’ okan gbogbo pes’ aye fun, Ki gbogb’ eda korin.
Read hymn : AYO b’ aiye: Oluwa deAYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni:
Read hymn : AYO kun okan wa loniAYO omo anu ti to! T’ o mo idariji: O nwip’ aiye ki se ‘le mi, Mo nwa ‘le mi s’ orun
Read hymn : AYO omo anu ti toBABA jowo gb’ adura wa, Bi a tin lo loju omi; Iwo ma je ebute wa, Si ma je ile isimi.
Read hymn : BABA jowo gb’ adura waBABA ma yi oju kuro Fun emi otosi; Ti np’ ohunrere ese mi N’ iwaju ite Re.
Read hymn : BABA ma yi oju kuroBABA mi, ‘gba mo nsako lo, Kuro l’ ona Re l’ aiye yi; Ko mi kin le bayi pe, Se ‘fe Tire.
Read hymn : BABA mi, ‘gba mo nsako loBABA orun! Emi fe wa N’ iwa mimo, l’ ododo; Sugbon ife eran’-ara Ntan mi je nigbagbogbo.
Read hymn : BABA orun! Emi fe waBABA orun, nin’ oro Re Ni ogo orun ntan; Titi lai l’ a o ma sin O, Fun Bibeli mimo.
Read hymn : BABA orun, nin’ oro ReBABA orun, ti ife Re B’ okan wa, wa irapada, A teriba niwaju Re, Jo fun wa n’ idariji Re.
Read hymn : BABA orun, ti ife ReBABA wa Olodumare, ‘Wo t’ o kawo igbi omi, ‘Wo t’ o ti f’ ipo okun fun. Ti ko le ri ibe koja;
Read hymn : BABA wa OlodumareBABA wa ti o mbe l’ orun, Owo l’ oruko Re, ‘Joba Re de, ife Re ni K’ a se bi ti orun.
Read hymn : BABA wa ti o mbe l’ orunBABA, a f’ ara wa, S’ iso Re l’ ale yi; Da bobo wa, k’ O pa wa mo, Tit’ ile o fi mo.
Read hymn : BABA, a f’ ara waBABA, a tun pade l’ oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re; Si O l’ a tun fe gb’ ohun wa s’ oke Lati wa anu, lati ko ‘rin ‘yin.
Read hymn : BABA, a tun pade l’ oko JesuBABA, aniyan at’ eru Le su l’ ojo ola, Sugbon ‘foya ko le wo ‘bi; Tire l’ ojo oni.
Read hymn : BABA, aniyan at’ eru