OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan
OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan, Yin oruko Re k’ a to tuka lo; N’ ipari sin, a dide lati yin: A ‘o si kunle fun ibukun Re.
Read hymn : OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kanOLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan, Yin oruko Re k’ a to tuka lo; N’ ipari sin, a dide lati yin: A ‘o si kunle fun ibukun Re.
Read hymn : OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kanIWO ti gbogbo eda nsin L’ ara erupe yi, Bi O tit obi to l’aiye! B’ ogo Re ti po to!
Read hymn : IWO ti gbogbo eda nsinOLORUN wa aiyeraiye, Ore Re ntan loke orun: Oto Re y’o la kuku ja Ti o bo ife Re loju.
Read hymn : OLORUN wa aiyeraiyeOKAN mi, tun rohin Enit anu Re, po, T’ ibinu Re ki ru Kankan, T’ o yara mu suru.
Read hymn : OKAN mi, tun rohinYIN ‘Luwa, okan mi; Ki gbogbo inu mi, Ba mi yin oruko Eni T’ ife Re po julo.
Read hymn : YIN ‘Luwa, okan miMO korin ipa Olorun, T’ O gbe oke dide, T’ O tan odo tin san kiri, T’ O si k’ orun giga.
Read hymn : MO korin ipa OlorunEJE k’ a f’ inu didun, Yin Oluwa Olore; Anu Re, o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : EJE k’ a f’ inu didunOLORUN l’ abo eni Re, Nigba iji iponju de: K’ awa to se aroye wa, A! saw o t’ On t’ iranwo Re.
Read hymn : OLORUN l’ abo eni ReYIN Olorun Oba wa, E ko orin ogo si, ‘Tor’ anu Re wa sibe, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReT’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun.
Read hymn : T’ OLORUN n’ ijoba gbogboONA ara l’ Olorun wa Ngba sise Re l’ aiye; A nri ‘pase Re lor’ okun, O ngun igbi l’ esin.
Read hymn : ONA ara l’ Olorun waOLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miSAJU wan so, Olorun, Fere ogun ti ro; Ninu papa isegun, N’ago Re l’ao ma gbe
Read hymn : SAJU wan so, OlorunAYO b’ aiye: Oluwa de! K’ aiye gba Oba re; K’ okan gbogbo pes’ aye fun, Ki gbogb’ eda korin.
Read hymn : AYO b’ aiye: Oluwa deMA wo ‘le, Jesu t’ a nreti, T’a bi lati gba ni la! Gba wa low’ ese at’ eru, K’ a r’ isimi ninu Re.
Read hymn : MA wo ‘le, Jesu t’ a nretiWO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora;
Read hymn : WO oju sanma ohun niGBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin
Read hymn : GBO ‘gbe ayo! Oluwa deILU t’ o dara po l’ aiye; Betlehem’, ‘wo ta won yo; Ninu re l’ Oluwa ti wa Lati j’ oba Israel’.
Read hymn : ILU t’ o dara po l’ aiyeODE, Kristi Oluwa, Lat’ ibugbe Re l’ orun, Lat’ ite alafia. O wa si aginju wa.
Read hymn : ODE, Kristi OluwaOJO ayo nlanla na de, Eyit’ araiye ti nreti; Nigbat’ Olugbala w’ aiye, Nigbat’ a bi ninu ara.
Read hymn : OJO ayo nlanla na deWO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ ogo;
Read hymn : WO! gbogbo ile okunkunGBO eda orun nkorin, “Ogo fun Oba t’ a bi.” “Alafia l’ aiye yi,” Olorun ba wa laja,
Read hymn : GBO eda orun nkorinAYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni:
Read hymn : AYO kun okan wa loni