BABA, je nya odun yi
BABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa:
Read hymn : BABA, je nya odun yi643 hymns
BABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa:
Read hymn : BABA, je nya odun yiBABA, mo n’ owo mi si O; Nko mo ‘ranwo miran: Bi O ba kuro lodo mi, A! nibo ni ngo lo?
Read hymn : BABA, mo n’ owo mi si OBABA, Omo, on Emi, Eni Metalokan lai, Jo, masai dabobo wa, K’ a le ri ‘mole ola.
Read hymn : BABA, Omo, on EmiBAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBELESE s’owo po, Ti nwon nde s’Oluwa, Dimo si Kristi Re, Lati gan Oba na,
Read hymn : BELESE s’owo poBENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin.
Read hymn : BENI, O bikita fun miBI a ti f’ okan wa fun O Nip’ ase mimo Re, Ran s’ or’ omi, ‘Daba orun, F’ edidi t’ eje na.
Read hymn : BI a ti f’ okan wa fun OBI agbonrin ti nmi hele, S’ ipa odo omi; Beni okan mi nmi si O, Iwo Olorun mi.
Read hymn : BI agbonrin ti nmi heleBI Jesu ba fe mi, Bi mo ba je Tire, Nko ko ohun t’ ota le ro, Bi nwon tile n’ ipa.
Read hymn : BI Jesu ba fe mi.BI mo egbarun ebun, Ngo di mo Jesu ti a pa, Y’o je ipile mi; ‘Tori ko s’ ipile miran,
Read hymn : BI mo egbarun ebunBI mo ti ri – laisawawi, Sugbon nitori eje Re, B’O si ti pe mi pe ki nwa – Olugbala, mo de.
Read hymn : BI mo ti ri – laisawawiBI o ti ri laisi ami Ife, ayo, tab’ ore kan, T’ o ye fun ibugbe orun, Elebi, ma bow a.
Read hymn : BI o ti ri laisi amiBI osun gbege eti ‘do, Tutu minimini; B’ igbo dudu eti omi, B’ itanna ipa ‘do.
Read hymn : BI osun gbege eti ‘doBIBELI mimo t’ orun Owon isura t’ emi! ‘Wo ti nwi bi mo ti ri, ‘Wo ti nso bi mo ti wa.
Read hymn : BIBELI mimo t’ orunBIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re?
Read hymn : BIBEL’ iwe aiyeraiyeBO ti dun to l’ oj’ owo yi, Ojo t’ o dara ju, Ki a pa ‘ronu aiye Ki a pa ‘ronu nkan t’ orun!
Read hymn : BO ti dun to l’ oj’ owo yiBUKUN ni fun ohun, T’ o de wa po n’nu ‘fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t’ orun.
Read hymn : BUKUN ni fun ohunB’ AWON ara igbani Ti f’ ayo ri ‘rawo na; Bi nwon ti f’ inu didun Tele ‘mole didan re;
Read hymn : B’ AWON ara igbaniB’ AYO aiye ti j’ asan to! Didara won ko pe! Ko s’ ayo ti ko l’ ororo, Adun re je ‘dekun.
Read hymn : B’ AYO aiye ti j’ asan toB’ ODO ti nyara san lo, Li ona gboro re, Ti omi re nja titi, T’ o nsare lo s’ okun,
Read hymn : B’ ODO ti nyara san loB’ ORUN l’ aiduro ti rin, La odun ti o lo ja Be l’ opo ti d’ opin won A ki o si ri won mo.
Read hymn : B’ ORUN l’ aiduro ti rinB’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro.
Read hymn : B’AIYE mi kun fun ‘banujeB’ENU mi dun bi t’ awon ju, T’ ede mi ta t’ angeli yo; Laisi ife mo dab’ ide, Ti ohun re nhan ni l’ eti.
Read hymn : B’ENU mi dun bi t’ awon juB’O ti dun lati gba Jesu Gbo gege bi oro Re; K’ a simi lor’ ileri Re, Sa gbogbo l’ Olyuwa wi.
Read hymn : B’O ti dun lati gba Jesu