K’ A to sun, Olugbala wa
K’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waK’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waOJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su.
Read hymn : OJO oni lo tanWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo.
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoBABA, a tun pade l’ oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re; Si O l’ a tun fe gb’ ohun wa s’ oke Lati wa anu, lati ko ‘rin ‘yin.
Read hymn : BABA, a tun pade l’ oko JesuIWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re.
Read hymn : IWO imole okan miOLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale wa dun.
Read hymn : OLUWA, ojo t’ O fun wa pinL’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo, Nwon gbe abirun wodo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ayo lo le won
Read hymn : L’ OJU ale, ‘gbat’ orun woIFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu:
Read hymn : IFE Re da wa si loniORUN si nyara wo, Ojo nku lo; K’ ife ko ji dide, K’ o rubo asale.
Read hymn : ORUN si nyara woOGO f’ Olorun l’ ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re.
Read hymn : OGO f’ Olorun l’ ale yiJESU, bukun wa k’ a to lo: Gbin oro Re si aiya wa: K’ o si mu k’ ife gbigbona Kun okan ilowo wa:
Read hymn : JESU, bukun wa k’ a to lo