OLUWA, alaimo l’ emi
OLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je.
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiOLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je.
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiOLUWA, a wa ‘do, Re, L’ese Re l’ a kunle si; A! ma kegan ebe wa, A o wa O lasan bi?
Read hymn : OLUWA, a wa ‘do, Re,OLUWA, Baba orun, B’ oju woo mo-‘do Re Ti nro t’ igbe aiye re, Ati ipo re si O.
Read hymn : OLUWA, Baba orunOLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku.
Read hymn : OLUWA, bawo l’ okan miOLUWA, b’ agbowode ni, Mo gb’ okan mi le O; Oluwa, f’ ore-ofe wi, K’ O se anu fun mi.
Read hymn : OLUWA, b’ agbowode niOLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi;
Read hymn : OLUWA, iji nfe s’ okeOLUWA, isimi Re dun; Sugbon t’ oke ju ti aiye lo; Sibe pelu ‘reti ayo Li okan ongbe wa nsare.
Read hymn : OLUWA, isimi Re dunOLUWA, Iwo l’ awa npe, A kunle siwaju ‘te Re, Nibo l’ alailera ‘ba lo, ‘Wo nikan ni nwon le kepe.
Read hymn : OLUWA, Iwo l’ awa npeOLUWA, jeki ore Re, To ‘lu wa pel’ agbara Re; K’ o le m’ eje ife re wa, Fun Iwo Olugbala wa.
Read hymn : OLUWA, jeki ore ReOLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni.
Read hymn : OLUWA, ki s’agbara miOLUWA, ma m’ oju kuro Lodo emi t’ o ny’ ile, Ti nsokun ese aiye mi, N’ ite anu ife Re.
Read hymn : OLUWA, ma m’ oju kuroOLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi.
Read hymn : OLUWA, mo gbo pe IwoOLUWA, nje ‘dariji Re Yio gb’ eni bi emi? Nje, O gbe ese mi kuro O f’ erin bukun mi?
Read hymn : OLUWA, nje ‘dariji ReOLUWA, Ob’ Alase, A wole ni ese Re; Gbo igbe itara wa, Bi O ba r’ oju, ao ku.
Read hymn : OLUWA, Ob’ AlaseOLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale wa dun.
Read hymn : OLUWA, ojo t’ O fun wa pinOLUWA, sanu, dariji; Da okan t’o yipada si; Ki sip e anu Re tobi Elese ko le ro mo O?
Read hymn : OLUWA, sanu, darijiOLUWA, y’o ti pe to T’ Iwo o tun pada; Are fere mu wa tan, Bi a ti nw’ ona Re;
Read hymn : OLUWA, y’o ti pe toOLUWA, ‘gbat’ a ngbadura Fun gbogbo enia, Gb’adura wa fun ile wa, Ile t’ a fe julo.
Read hymn : OLUWA, ‘gbat’ a ngbaduraOLUWA alafia wa L’ O pase t’ odun yipo; Awa omo Re wa dupe F’ odun titun t’ a bere.
Read hymn : OLUWA alafia waOLUWA at’ ‘igbala wa, L’ o ko wa jo l’ ale oni, Je ka gbe Ebeneser ro; Odun t’ a ti la koja yi,
Read hymn : OLUWA at’ ‘igbala waOLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro.
Read hymn : OLUWA fi apa Re hanOLUWA ib’ isadi mi, ‘Wo ni mo gbekele; Oro Re gba mi n’ iyanju, Emi erupe ‘le.
Read hymn : OLUWA ib’ isadi mi“OLUWA ji loto:” O wa ko ni ku mo, O wa lati be f’ elese, Ti o ru egan won.
Read hymn : OLUWA ji lotoOLUWA l’ atilehin mi, Kini ‘ba te mi ri? Eniti O da aiye ro, T’ O ta sanma l’ aso.
Read hymn : OLUWA l’ atilehin mi