MO ti se ‘leri, Jesu
MO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi,
Read hymn : MO ti se ‘leri, JesuMO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi,
Read hymn : MO ti se ‘leri, JesuJESU alail’ abawon, O ti f’ eje Re ra mi, Nko nani ohunkohun, Lehin agbelebu Re.
Read hymn : JESU alail’ abawonJI, okan mi, dide giri, Ma lepa nso kikan; F’ itara sure ije yi F’ orun, f’ ade iye.
Read hymn : JI, okan mi, dide giriOJISE Krist’, dide, E mura fun ‘se na, Iri ‘bukun lat’ orun wa Ti se s’ ori ile.
Read hymn : OJISE Krist’, dideKO mi, Oluwa mi, Ki nr’ owo Re yika, Ki nsi ma se ohun gbogbo, Bi enipe fun O.
Read hymn : KO mi, Oluwa miOG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu, Ona Re si yato; Ko si j’ ohun t’ o wu eda, Lati fi iyin fun.
Read hymn : OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanuSISE tori oru mbo ! Sise li owuro; Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna; Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran, Sise tori oru mbo ! ‘gb ise o pari.
Read hymn : SISE tori oru mbo ! Sise li owuroSISE, akoko nlo, Se tokantokan; Sise, okan nsegbe, Sise, oru mbo,
Read hymn : SISE, akoko nloARA mi fun ‘rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sise l’ oruko Jesu, Tit’ On o tun pada, wa,
Read hymn : ARA mi fun ‘rugbin rereAO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni wa, Jek’ a tele ona ti Oluwa wa to; K’ a f’ imoran Re so agbara wa d’ otun, K’ a fi gbogbo okun wa sise t’ a o se.
Read hymn : AO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni waYO awon ti nsegbe, sajo eni nku, F’ anu ja won kuro ninu ese, Ke f’ awon ti nsina, gb’ eni subu ro, So fun won pe, Jesu le gba won la,
Read hymn : YO awon ti nsegbe, sajo eni nkuAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re?
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi bi