KO s’ aye ‘jafara nihin
KO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihin643 hymns
KO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihinKO s’ ohun t’ o ku kin se, B’ o ti wu k’ o kere; Jesu ku, O san gbogbo Igbese ti mo je.
Read hymn : KO s’ ohun t’ o ku kin seKo s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orunKO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Read hymn : KO s’ ore bi Jesu onireleKO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de.
Read hymn : KO to k’ awon mimo beruKRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun;
Read hymn : KRIST, ologo, ololaKRISTI fun gbogb’ aiye Ise nla naa bere Egbegberun ni gbogb’ aiye, Nfe gb’ oro ‘mo ‘Lorun
Read hymn : KRISTI fun gbogb’ aiyeKRISTI n’ ipile wa, Lori Re lao kole; Awon mimo nikan, L’ o ngb’ agbala orun.
Read hymn : KRISTI n’ ipile waKRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora.
Read hymn : KRISTIAN ma ti wa ‘simi,KRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese.
Read hymn : KRIST’ ki ‘joba Re deKRIST’ Oluwa ji loni, – Halleluyah, Eda at’ Angeli nwi – Hal. Gb’ ayo at’ isegun ga – Hal. K’ orun at’ aiye gberin! – Hal.
Read hymn : KRIST’ Oluwa ji loni, – HalleluyahKRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji
Read hymn : KRIST’, nin’ ogba EdenK’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waK’ OLORUN so o, k’ a tun pade Ki imoran Re gbe o ro, K’ O ka o mo agutan Re, K’ Olorun so o, k’ a tun pade!
Read hymn : K’ OLORUN so o, k’ a tun padeK’ ORE-ofe Krist’ Oluwa, Ife Baba ailopin, Oju rere Emi Mimo K’ o t’ oke ba lori wa.
Read hymn : K’ ORE-ofe Krist’ OluwaLAB’ agbelebu Jesu Mo fe lati duro, – Oji apata titobi Ninu ile are,
Read hymn : LAB’ agbelebu JesuLAB’ ese, ati l’ oke wa, Ni ikilo tin dun, Oku aimo ‘ye sun n’nu ‘le, Orun si wa l’ oke.
Read hymn : LAB’ ese, ati l’ oke wa“LAI lodo Oluwa!” Amin, beni k’o ri, Iye wa ninu oro na, Aiku ni titi lai,
Read hymn : LAI lodo OluwaLAIFOYA l’apa Jesu, Laifoya l’aiya Re, Labe ojij’ife Re, L’okan mi o simi.
Read hymn : LAIFOYA l’apa JesuLALA alagbase tan; Ojo ogun ti pari; L’ ebute jinjin rere Ni oko re ti gun si;
Read hymn : LALA alagbase tanLARIN ewu at’ osi, Kristian, ma te siwaju, Roju duro, jija na, K’ onje ‘ye mu o l’ okun.
Read hymn : LARIN ewu at’ osi.LASAN l’ adun aiye npe mi; Mo fe ki njo Jesu, Ohun aiye ko da mi ro; Mo fe ki njo Jesu.
Read hymn : LASAN l’ adun aiye npe miLASAN ni ero mi nwa ‘pa, T’ o ye fun okan mi kiri; Okan mi ko le n’ isimi, Tor’ aiye ko le bukun mi.
Read hymn : LASAN ni ero mi nwa ‘paLAT’ oke tutu Grinland, Lati okun india, Nib’ odo orun Afrik’, Nsan ‘yanrin wura won;
Read hymn : LAT’ oke tutu Grinland