IKU l’ opin ohun gbogbo
IKU l’ opin ohun gbogbo; B’ o ti wu k’ emi gun, Egun ni ko le sai ma se T’ a ti fi eda gun.
Read hymn : IKU l’ opin ohun gbogboIKU l’ opin ohun gbogbo; B’ o ti wu k’ emi gun, Egun ni ko le sai ma se T’ a ti fi eda gun.
Read hymn : IKU l’ opin ohun gbogbo“O SUN,” ni Jesu wi Nipa ti Lasaru, Enit’ o ku, ti a ti san, T’ a ti te s’ iboji.
Read hymn : O SUN,” ni Jesu wiGBAT’ a kun fun ‘banuje, Gb’ omije nsan l’ oju wa, Gbat’ a nsokun, t’ a nsofo, Olugbala, gbo ti wa.
Read hymn : GBAT’ a kun fun ‘banuje,ITANA t’ o bo ‘gbe l’ aso, T’o tutu yoyo be; Gba doje ba kan, a si ku, A subu, a siro.
Read hymn : ITANA t’ o bo ‘gbe l’ asoRANSE Olorun seun; Simi n’nu lala re; Iwo ti ja, o si segun; Bo s’ ayo Baba re,
Read hymn : RANSE Olorun seunMA sun lo, olufe; sa ma simi, F’ ori re le aiya Olugbala; A fe o, sugbon Jesu fe o ju:- O di owuro o!
Read hymn : MA sun lo, olufe; sa ma simiKI a to d’ awon oke nla, Tabi ki aiye to duro, Ki a to da awon igba, ‘Wo l’ Olorun lat’ ibere.
Read hymn : KI a to d’ awon oke nlaLALA alagbase tan; Ojo ogun ti pari; L’ ebute jinjin rere Ni oko re ti gun si;
Read hymn : LALA alagbase tanIBUKUN ni f’ oku, T’ o simi le Jesu; Awon t’ o gb’ ori won Le okan aiya Re.
Read hymn : IBUKUN ni f’ okuGB’ ohun to t’ orun wa ti wi, Bukun f’ oku onigbagbo Nwon bo ninu lala aiye Aiye ki yio tun mo won mo,
Read hymn : GB’ ohun to t’ orun wa ti wiNIGBAT’ ipe ba dun, Ngo dide n’nu ‘boji, Ngo r’ Onidajo Alade, Ri sanma t’ o ngbina.
Read hymn : NIGBAT’ ipe ba dunNJ’ Onidajo yio wa? Nj’ oku yio ji dide? Nje ko s’ eniti yio le sa Kuro ni oju Re?
Read hymn : NJ’ Onidajo yio waGBA ‘Wo Onidajo ba de Lati m’ awon Tire lo ‘le, Ngo ha wa l’ arin won? Ao ha r’ ekolo lasan yi,
Read hymn : GBA ‘Wo Onidajo ba deKO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihinJESU Oluwa mbo, Lati se ‘dajo wa, Yio san f’ olukuluku, Gege bi ise re.
Read hymn : JESU Oluwa mboGBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe!
Read hymn : GBAT’ O ba de, gbat’ O ba deOJO ‘dajo, ojo, eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye.
Read hymn : OJO ‘dajo, ojo, eruNIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile.
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoJERUSALEM ibi ayo, T’ o se owon fun mi; ‘Gbawo n’ ise mi yio pari, L’ ayo, l’ alafia?
Read hymn : JERUSALEM ibi ayoLEHIN odun die, Lehin igba die, A o ko wa jo pel’ awon Ti o sun n’ iboji.
Read hymn : LEHIN odun dieJERUSALEM t’ orun, Orin mi, ilu mi! Ile mi bi mba ku, Ekun ibukun mi;
Read hymn : JERUSALEM t’ orunILE ewa wonni, b’ o ti dara to! Ibugbe Olorun, t’ oju ko ti ri; Tal’ o fe ibe, lehin aiye yi? Tal’ o fe k’ a wo on ni aso funfun?
Read hymn : ILE ewa wonni, b’ o ti dara toOKAN are, ile kan mbe, Jina rere s’ aiye ise; Ile t’ ayida ko le de, Tani fe lo simi nibe?
Read hymn : OKAN are, ile kan mbeILE ayo kan wa Ti o Jina, Ti awon mimo wa; Nwon nran b’ orun;
Read hymn : ILE ayo kan wa