
GB’ ori soke alare
1. GB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro, Refrain Ayo ma nbo

1. GB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro, Refrain Ayo ma nbo

1. F’ORUKO Jesu s’ okan re Om’ egbe on ‘banuje; Yio fun o l’ayo oun ‘tunu Gbee wo lo s’ibi gbogbo Ooko ‘re… ti dun

1. KO si ewa nibikan ti Mo le fi we ti Krist’: Ohun t’ oku, Oluwa, ni K’ a je ‘kan pelu Re. 2. Mu

1. NGO fe O, Olorun Baba, Olugbala, Oba mi; Ngo fe O, ‘tori laisi Re Aiye j’ ohun kikoro. 2. Ngo fe O, gbogbo ibukun

1. MO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado; On ni enikan

1. MO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku, Mo fe O, Olorun,

1. Ife orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo Riri ife

1. NGO feran Re, Wo odi mi; Ngo feran Re, ‘Wo ayo mi; Ngo feran Re, patapata; Ngo feran Re, tor’ ise Re, Ngo feran

1. B’ORUKO Jesu ti dun to L’ eti olugbagbo! O tan ‘banuje on ogbe, O le eru re lo. 2. O mu ogbe emi re

1. OKAN mi, Oluwa ni, Jesu re ni, gb’ oro Re; Jesu nso, O mba o so, Pe, “Elese, ‘wo fe mi?” 2. ‘Gbat’ a
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar