JESU l’ Olusagutan mi
1. JESU l’ Olusagutan mi,Ore Eniti ki ye!Ko s’ ewu bi mo je Tire,T’ On sije t’ emi titi. 2. Nib’ odo omi iye nsanNibe
1. JESU l’ Olusagutan mi,Ore Eniti ki ye!Ko s’ ewu bi mo je Tire,T’ On sije t’ emi titi. 2. Nib’ odo omi iye nsanNibe
1. EFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
1. mJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife. 2. Wa, je k’
1. EYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo. 2. Oluwa On ni Olorun, T’
1. OWO at’ Alabukunfun Ni ile t’ o jewo Jesu, Okan at’ ile na l’ ayo Nibiti Olugbala wo. 2. Gb’ ori s’ oke, ilekun
1. NIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun. 2. Ipa Re
1. E Yin Oluwa, e tun ohun se, Lati korin Re ninu ajo nla; E je k’ aiye yo ninu Eleda won, K’ akobi igbala
1. DIDUN n’ ise na, Oba mi, Lati ma yin oruko Re, Lati se ‘fe Re l’ owuro, Lati so-oro Re l’ale. 2. Didun l’ojo
1. EWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin.
1 YIN Oluwa, oro didun Yin oru ‘dake je, Gbogbo aiye so ogo Re, Yin, irawo ‘mole. 2. Yin, enyin iji t’ o dide N’
We promise not to spam you