
JESU wipe k’ a ma sora
1. JESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re. 2. Jesu wipe ka

1. JESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re. 2. Jesu wipe ka

1. OKAN wa ji; k’ eru fo lo, Ki gbogbo ifoiya k’o lo; Ji, k’ o sis are ‘je orun, Si fi igboiya ayo han.

1. OM’-OGUN Krist’ dide Mu ‘hamora nyin wo; Mu ‘pa t’ Olorun fi fun nyin, Nipa ti Omo Re. 2. Gbe ‘pa Olorun wo, T’

1. EMA te siwaju, Kristian ologun, Ma tejumo Jesu t’ O mbe niwaju Kristi Oluwa wa ni Balogun wa, Wo! asia Re wa niwaju ogun;

1. HA! egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele Ogun Jesu fee de na, A fere segun! “D’ odi mu, emi fere de,”

1. KRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora. 2. Ogun orun apadi, T’ a ko ri

1. DURO, duro fun Jesu, Enyin om’ogun Krist’: Gbe asia Re s’ oke, A ko gbodo fe ku; Lat’ isegun de ‘segun N’ y’o ma

1. BABA orun, nin’ oro Re Ni ogo orun ntan; Titi lai l’ a o ma sin O, Fun Bibeli mimo. 2. Opo ‘tunu wa

1. A, JEKI oro mimo Re Fi agbara si okan mi, F’ imole at’ ife orun Wi f’ okan mi pe, “Wo t’ emi.” 2.

1. BIBELI mimo t’ orun Owon isura t’ emi! ‘Wo ti nwi bi mo ti ri, ‘Wo ti nso bi mo ti wa. 2. ‘Wo
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar