
OJISE Krist’, dide
1. OJISE Krist’, dide, E mura fun ‘se na, Iri ‘bukun lat’ orun wa Ti se s’ ori ile. 2. Lo toju alaisan, At’ awon

1. OJISE Krist’, dide, E mura fun ‘se na, Iri ‘bukun lat’ orun wa Ti se s’ ori ile. 2. Lo toju alaisan, At’ awon

1. KO mi, Oluwa mi, Ki nr’ owo Re yika, Ki nsi ma se ohun gbogbo, Bi enipe fun O. 2. Gbogbo aiye le se

1. OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu, Ona Re si yato; Ko si j’ ohun t’ o wu eda, Lati fi iyin fun. 2. Ibukun ni

1. SISE tori oru mbo ! Sise li owuro; Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna; Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran,

1. SISE, akoko nlo, Se tokantokan; Sise, okan nsegbe, Sise, oru mbo, N’nu ogba Oluwa Lo sise loni, Ma duro laise nkan, Mase jafara. 2.

1. ARA mi fun ‘rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sise l’ oruko Jesu, Tit’ On o tun pada, wa, Nigbana ni a o f’ayo

1. AO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni wa, Jek’ a tele ona ti Oluwa wa to; K’ a f’ imoran Re so agbara

1. YO awon ti nsegbe, sajo eni nku, F’ anu ja won kuro ninu ese, Ke f’ awon ti nsina, gb’ eni subu ro, So

1. AJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re? 2. Ao ha gbe mi g’ oke

1. MA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le. 2. Ma ja, ma gbadura,
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar