
A IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa
1. A IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’

1. A IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’

1. OLORUN Olodumare, Alanu, Olore, Iwo l’ O da gbogbo aiye, Ati orun pelu. 2. Gbat’ O da Adam’, baba wa S’ inu ogba Eden’,

1. OLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni. 2. B’emi mi

1. B’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro. 2. Emi kio

1. ONA Re, Oluwa, B’ o ti wu k’ o su to, Masai f’ owo ‘tun Re to mi, Yan ipa mi fun mi. 2.

1. MA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu, Onje orun, Ma

1. BABA mi, ‘gba mo nsako lo, Kuro l’ ona Re l’ aiye yi; Ko mi kin le bayi pe, Se ‘fe Tire. 2. B’

1. MO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi, Emi k’ y’o beru ogun,

1. JESU alail’ abawon, O ti f’ eje Re ra mi, Nko nani ohunkohun, Lehin agbelebu Re. 2. Tire nikan ni mo je, O fun

1. JI, okan mi, dide giri, Ma lepa nso kikan; F’ itara sure ije yi F’ orun, f’ ade iye. 2. Awosanma eleri wa, Ti
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar