
JESU, nigba aiye Re
1. JESU, nigba aiye Re, O ko dekun wo arun; Igbe irora aisan Ko kan O k’ o bo ‘le ri. 2. Oju anu Re

1. JESU, nigba aiye Re, O ko dekun wo arun; Igbe irora aisan Ko kan O k’ o bo ‘le ri. 2. Oju anu Re

1. ESE t’ onigbagbo mberu? Kini ‘ba ma da won l’ amu? Iku Jesu le ‘foya lo, O mu isimi sokale. 2. Kil’ olori edun

1. OM’ Olorun, a ko ri O, ‘Gbat’ O wa s’ aiye iku yi; Awa ko ibugbe Re, Ni Nasareti ti a gan; Sugbon a

1. IGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye. 2. Igbagbo ni keke Enok’

1. OLORI ijo t’ orun, L’ ayo l’ a wole fun O; K’ o to de, ijo t’ aiye, Y’o ma korin bi t’ orun,

1. TANI yio gbe Jabob’ dide?” Ore Jakob’ kop o; Eyi t’ o je ‘yanu nip e, Imo won ko s’ okan. 3″Tani yio gbe

1. OLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses; Olorun ti mo tele Pe,

1. NIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.

1. LARIN ewu at’ osi, Kristian, ma te siwaju, Roju duro, jija na, K’ onje ‘ye mu o l’ okun. 2. Kristian, ma se te

1. EREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun?
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar