
LASAN ni ero mi nwa ‘pa
1. LASAN ni ero mi nwa ‘pa, T’ o ye fun okan mi kiri; Okan mi ko le n’ isimi, Tor’ aiye ko le bukun

1. LASAN ni ero mi nwa ‘pa, T’ o ye fun okan mi kiri; Okan mi ko le n’ isimi, Tor’ aiye ko le bukun

1. JESU b’ oluso, ma sin wa, A nfe, ki Re pupo; F’ onje didara Re bow a, Tun agbo Re se fun wa; Olugbala

1. BABA, a f’ ara wa, S’ iso Re l’ ale yi; Da bobo wa, k’ O pa wa mo, Tit’ ile o fi mo.

1. BABA, Omo, on Emi, Eni Metalokan lai, Jo, masai dabobo wa, K’ a le ri ‘mole ola.

1. ONTO mi lo iro ‘bukun, Oro t’ orun tu mi ninu, Ohun ti o wu kemi se Sibe Olorun nto mi lo. Refrain Onto

1. IGBALA ni, igbala ni, Awa elese nfe; Nitori ninu buburu, T’ a se l’ awa nsegbe. 2. Ise owo wa ti a nse, O

1. ITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si, Itan iyanu t’ ife! Ti dun l’eti kikan! Awon Angeli rohin re, awon oluso si

1. JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le O npe loni, o npe loni! Ese t’ o fi ko ife Re sile, T’ o

1. A KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa. 2. A

1. OBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘se On la mu wa fi sun niwaju Jesu; Jesu terire ba. O nkowe n’ ile; T’ agba
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar