
JESU fe k’ emi je ‘mole
1. JESU fe k’ emi je ‘mole, Ki ntan lojojumo; Nibi gbogbo kin le wu On, N’ ile, ni skul, l’ode. Imole, imole, Jesu fe’

1. JESU fe k’ emi je ‘mole, Ki ntan lojojumo; Nibi gbogbo kin le wu On, N’ ile, ni skul, l’ode. Imole, imole, Jesu fe’

GBOGBO aiye ti nu s’ okunkun ese Imole aiye ni Jesu! B’ iran orun l’ osan gangan l’ ogo Re, Imole aiye ni Jesu, Refrain

1. JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan, Bi fitila kekere ninu oru; L’ aiye okunkun yi, ka si tan, N’ ipo

1. JESU ni gbogb’ aiye fun mi, Iye at’ ayo mi, Agbara mi lojojumo, L’ aisi Re mo subu; Ni ‘banuje On ni mo to,

1. KO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’

1. LASAN l’ adun aiye npe mi; Mo fe ki njo Jesu, Ohun aiye ko da mi ro; Mo fe ki njo Jesu. Refrain Ki

1. MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo, On na ko ko ni bi ore aiye sa; Tifetife li on nse ajo lori mi,

1. MO n’ ‘ore, kan, A, Ore na! N’ ife mi k’ emi to mo, On f’ okun ife Re nla, Fa mi sunmo odo

1. OLUSAGUTAN ni npe mi, Kuro nin aginju ese, On p’ agutan t’ o sako lo Jina rere sinu agbo. Refrain Mu won wa, mu

1. B’ IFE Olugbala ti dun to! Bi t’ okun iwon re tayo; Ewa didara re julo ni Pe o to tile ndun si ni
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar