
A RE mu o okan re poruru
1. A RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu

1. A RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu

1. B’O ti dun lati gba Jesu Gbo gege bi oro Re; K’ a simi lor’ ileri Re, Sa gbogbo l’ Olyuwa wi. Refrain Jesu,

1. T’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo; Ti giga

1. NWON duro fun ete kan Nwon gbo t’Olorun; Bola fun Olotito K’a nyin egbe Daniel – Refrain Ki a se bi Daniel, K’a fi

1. ENIKAN se ise wura; On wa b’ ore nigba aini; Enikan ko orin ayo, Nmu sanma dan ni gbogb’ ojo. Refrain Eni na ni

1. ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po, Ife nla ti ko le sa, Bi mo tile s’ aito, S’ife Re yi

1. GBATI ipe Oluwa ba dun T’ akoko ba si pin, T’ imole owuro mimo ntan lailai; Gbat’ awon t’ a ti gbala, Y’o pejo

1. IJA ti de, ipe sin dun kikankikan, “Wo ‘hamora!” nigbe jake-jado; Oluwa omo-ogun nlo si isegun, Ko pe ti segun Krist’ y’o farahan. Refrain

1. IMOLE k’ okan mi loni, T’ o logo t’ o si ndan, T’ o tan ju t’ awosanma lo, Jesu n’ imole mi. Refrain

1. IWO ha nberu p’ ota yio segun? Okun su lode o sis u ju ninu? Si ferese ati ilekun sile, Jeki ‘ran orun wole.
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar