
OLORUN so wa n’nu oko
1. OLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba

1. OLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba

1. APATA wa n’ ile are, Ojiji Re bo si iyanrin, O npe awon ero ti nkoja, Lati wa si boji l’ aginju. Refrain Etise

1. GBATI ‘ji goke l’ ona re, T’ o f’ aniyan kun okan mi, N’ gbekele w’ oke, wipe, “Mo mo p’ Oluwa wa n’

1. SION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan

1. JE ran orun kekere nibiti o nlo, Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye, ‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro, B’

1. ITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole, Itan alafia

1. NGO je ‘mole fun Jesu, Ki ntan nigba gbogbo, Ki ntan s’ ibi to fe mi, Ki ntan l’ojojumo, L’ oro ‘fe ati n’

1. WA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun, Krist, t’ O jinde n’ipa, Krist, t’ O de nyin l’ ade, On

1. A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke Refrain Halleluya, tire logo Halleluya, Amin; Halleluya,

ORIN t’o dun wa s’okan mi, Orin ayo inu-didun, Ngo korin alafia didun, Ebun ife t’Olorun. Refrain A- la-fi-a; Ebun ‘yanu lat’ orun! Alafia t’o
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar