
OLORUN mi! Olorun mi
1. OLORUN mi! Olorun mi! Mo f’ ara mi fun O; Dari aisedede ji mi, Ma je ki nsako mo, F’ oju anu wo mi,

1. OLORUN mi! Olorun mi! Mo f’ ara mi fun O; Dari aisedede ji mi, Ma je ki nsako mo, F’ oju anu wo mi,

KI se l’ ainireti, Ni mo to o wa, Ki se l’ aini ‘gbagbo, Ni mo kunle; Ese ti gori mi, Eyi sa l’ ebe

1. ALEJO kan ma nkankun, Pe E wole O ti npara ‘be tip e Pe E wole. Pe wole ki o to lo, Pe wole,

1. ETUN won ko fun mi ki ngbo Oro ‘yanu t’ Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro ‘yanu t’ Iye, Oro iye

1. MO fi gbogbo re fun Jesu Patapata laiku kan; Ngo ma fe ngo si gbekele, Ngo si ma ba gbe titi. Refrain Mo fi

1. OLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti

1. MO Fe mo nipa Jesu sii, F’or’ ofe Re h’ elomiran; Ki nle ri ‘gbala kikun Re, Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku

1. GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye Nn’ orin at’adura, ale; N’ alo at’ ife eba ina, Ibagbe re si wa yi wa ka, ‘Gbagbo’

1. BABA jowo gb’ adura wa, Bi a tin lo loju omi; Iwo ma je ebute wa, Si ma je ile isimi. 2. Jesu Olugbala

1. BABA wa Olodumare, ‘Wo t’ o kawo igbi omi, ‘Wo t’ o ti f’ ipo okun fun. Ti ko le ri ibe koja; Gbo
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar