
KO s’ ohun t’ o ku kin se
1. KO s’ ohun t’ o ku kin se, B’ o ti wu k’ o kere; Jesu ku, O san gbogbo Igbese ti mo je.

1. KO s’ ohun t’ o ku kin se, B’ o ti wu k’ o kere; Jesu ku, O san gbogbo Igbese ti mo je.

1. EYI, e yipada, ese t’ e o ku, Nigbat’ Olorun sunmo wa li anu? Jesu npe nyin, Emi sin wipe k’ e wa, Angeli

1. ALAFIA w’ okan, t’ ohun re Ko apata l’ ohun aro: Dekun ejo wi, pa ‘nu mo, Ki ekun ye san l’ oju re;

1. ARE mu o, aiye su o, Lala po fun o? Jesu ni, “Wa si odo, Mi, K’ o simi.” 2. Ami wo l’ emi

1. ENYIN omo oku, T’ o wa ninu ese, Gb’ ohun ihinrere, Jesu ranse si iyin. Enyin ent-egbe, e wa; Ni apa Jesu, aye mbe.

1. JESU npe wa l’ osan, l’ oru Larin irumi aiye; Lojojumo l’ a ngb’ ohun Re Wipe, “Kristian, tele Mi.” 2. Awon Apostili ‘gbani,

1. WA sodo Jesu, mase duro, N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi jeje

1. GBO okan mi, bi Angeli ti nkorin, Yika orun ati yika aiye; E gbo bi oro orin won ti dun to! Ti nso ‘gbati

1. “WA sodo Mi, alare Ngo fun nyin n’ isimi.” A! ohun didun Jesu, Ti o p’ elese wa, O nso ti ore ofe, Ati

1. NIGBAT’ idanwo yi mi ka, T’ idamu aiye mu mi, Ti Esu wa bi ore mi, Lati wa iparun mi. Oluwa, jo masai pe
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar