
YIN Olorun Oba wa
1. YIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju. 2. Yin Enit’ oda, orun Ti o

1. YIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju. 2. Yin Enit’ oda, orun Ti o

1. GB’ ope mi, Oluwa, Lat’ okan l’ o ti wa, Iwo t’ O gba die opo, K’yo kegan ‘more mi. 2. Tire ‘ eran

1. A F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo; Gbat’ a wa l’ omowo On

1. AWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u. 2. Ibukun f’ awon to fe, Irora n’nu

1. OLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.

1. WA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de. 2. Ife rere

1. AYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa. 2. Larin egbegberun ‘danwo,

1. OLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro. 2. K’

1. OJO ati akoko nlo, Nwon nsun wa s’ eti ‘boji; Awa fere dubule na, Ninu iho ‘busun wa. Refrain K’ a ba O gbe,

1. BABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa: Bi ‘banuje on ‘rora Nko gbodo
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar