
JESU a w’ odo Re
1. JESU a w’ odo Re L’ ojo Re mimo yi; To wa wa ba wa ti pejo, Si ko wa fun ‘ra Re. 2.

1. JESU a w’ odo Re L’ ojo Re mimo yi; To wa wa ba wa ti pejo, Si ko wa fun ‘ra Re. 2.

1. FI ibukun Re tu wa ka, Fi ayo kun okan wa; K’ olukuluku mo ‘fe Re, K’ a l’ ayo n’ nu ore Re,

1. OLORUN awa fe, Ile t’ ola Re wa; Ayo ibugbe Re Ju gbogbo ayo lo. 2. Ile adura ni, Fun awon omo Re Jesu

1. LI o wuro Iwo o gbo Ohun mi, Oluwa; S’ odo Re l’ emi o dari Oju adura mi. 2. Si oke ti Jesu

1. NI kutu, mo de Oluwa Lati wa oju Re, Okan ongbe mi da ‘ku lo, Lais’ ayo ore Re. 2. B’ o ti wu

1. JESU bukun oro Re, K’ o le tete f’ ipa han; Ki elese gbo ‘pe Re, K’ enia Re dagba n’nu ‘fe. 2. Bukun

1. AKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo. 2. Gbat’

1. JI okan mi, ba orun ji, Mura si ise ojo re; Ma se ilora, ji kutu, K’ o san ‘gbese ebo oro. 2. Ogo

1. OLORUN kutu ohun Re L’ o mu orun f’ ayo dide, Inu re dun bi omiran, Lati sare yi sanma ka. 2. Gege bi

1. GBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi, K’o le
We promise not to spam you