
GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de
1. GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe! Bi irawo owuro, nwon

1. GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe! Bi irawo owuro, nwon

1. OJO ‘dajo, ojo, eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye. Bi esun na Yio

1. NIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile. Ewu on ‘banuje Wa yi mi kakiri; Orun ni ilu

1. JERUSALEM ibi ayo, T’ o se owon fun mi; ‘Gbawo n’ ise mi yio pari, L’ ayo, l’ alafia? 2. ‘Gbawo ni oju mi

1. LEHIN odun die, Lehin igba die, A o ko wa jo pel’ awon Ti o sun n’ iboji. Jesu Oluwa mi! Mu mi mura

1. JERUSALEM t’ orun, Orin mi, ilu mi! Ile mi bi mba ku, Ekun ibukun mi; Ibi ayo! Nigbawo ni, Ngo r’ oju re, Olorun

1. ILE ewa wonni, b’ o ti dara to! Ibugbe Olorun, t’ oju ko ti ri; Tal’ o fe ibe, lehin aiye yi? Tal’ o

1. OKAN are, ile kan mbe, Jina rere s’ aiye ise; Ile t’ ayida ko le de, Tani fe lo simi nibe? Duro…. roju duro,

1. ILE ayo kan wa Ti o Jina, Ti awon mimo wa; Nwon nran b’ orun; A! nwon nkorin didun, Yiye l’ Olugbala wa, Ki

1. JEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba. 2.
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar