
OKAN mi, oju re tun ri
1. OKAN mi, oju re tun ri Afemo ju ojo; Lekan si, korin, ohun mi S’ Oba t’ O je loke. 2. Oru d’oru np’

1. OKAN mi, oju re tun ri Afemo ju ojo; Lekan si, korin, ohun mi S’ Oba t’ O je loke. 2. Oru d’oru np’

1. NIGBAT’ imole owuro Ba nti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi! Tu isudede ebi ka

1. KRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun; ‘Mole oro sunmo mi, ‘rawo oro, w’aiya mi. 2. Okunkun

1. OTUN ife l’ o nfarahan, Bi a ti nji l’ ojojumo, Lat’ inu orun at’ okun, A ji s’ agbara at’ ero. 2. Otun

1. JESU, Oluwa or’-ofe, ‘Wo imole oju Baba, Kanga ‘mole aiyeraiye, T’ ase Re l’ okun ale lo. 2. Wa, Orun ‘fe orun mimo, Ran

1. NINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba. 2. Oluwa pa wa

1. OLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise. 2.

1. MIMO, mimo, mimo! Olodumare! Ni kutukutu n’Iwo o gbo orin wa; Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo! Ologo meta lai, Olubukun! 2. Mimo, mimo, mimo!

1. MO fe iyera s’ apakan Kuro l’ ero t’ aiye, Ki nf’ akoko iwo orun Kunle gba adura. 2. Mo few a nikan ki

1. JE ni imole ojo Para kuro loju mi, Lala mi rekoja lo, Ngo ba Oluwa soro. 2. ‘Wo t’ oju Re ri yika, Oba
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar